Non-Orisha Initiate Mojuba Prayer
Consult with house elder if you have questions.
(Drop 3 drops of water on the floor while repeating the following lines)
Omi Tutu
Ona Tutu
Ile Tutu
Ori Tutu
Elegba Tutu
Mojuba Olofi
Mojuba Olodumare
Mojuba Eshu / Elegba
Mojuba Ogun
Mojuba Ochosi
Mojuba Obatala
Mojuba Oya
Mojuba Yemaya
Mojuba Shango
Mojuba Oshun
Mojuba Gbogbo Orisha
Mojuba Olorun (Heaven)
Mojuba Imales (Elders at the foot of Olofi)
Mojuba Adumale
Mojuba Acoba (Good) / Mojuba Acheda (Bad)
Mojuba Gbogbo Ara Orun (Spiritual Beings)
Iba Baba (I Salute My Father)
Iba Yeye (I Salute My Mother)
Iba (Deceased relative’s name)
Iba (Deceased relative’s name)
Iba (Deceased relative’s name)
Iba Gbogbo Egun
Iba se Oluwosi
Dropping water on the floor only:
Living Elders of Osha
Ki Nkan Ma Se Ibu Elemi (God Parent’s Name – Cheryl Gayle)
Ki Nkan Ma Se Oke Ewe (Your Adjubone’s name if appropriate)
Ki Nkan Ma Se Abitoye (Baba Sean/ Padrino Name – Babalowo)
Dropping water on the floor only:
Ko Si Iku (Death)
Ko Si Arun (Sickness)
Ko Si Epe (Curses)
Ko Si Oran (Big Trouble)
Ko Si Ofo (Loss)
Ko Si Araye (Tragedy)
Ko Si Fitibo (Being Overwhelmed)
Ko Si Egba (Paralysis)
Ko Si Ese (Evil)
Ariku Babawa: Let us not see Death, Our Father
Ariku Iyawa: Let us not see Death, Our Mother